Hos 8:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nwọn ti gbìn ẹfũfũ, nwọn o si ka ãjà: kò ni igi ọka: irúdi kì yio si mu onjẹ wá: bi o ba ṣepe o mu wá, alejò yio gbe e mì.

Hos 8

Hos 8:3-11