Hos 8:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. FI ipè si ẹnu rẹ. Yio wá bi idì si ile Oluwa, nitori nwọn ti re majẹmu mi kọja, nwọn si ti rú ofin mi.

2. Nwọn o kigbe si mi pe, Ọlọrun mi, awa Israeli mọ̀ ọ.

3. Israeli ti gbe ohunrere sọnù; ọta yio lepa rẹ̀.

Hos 8