Hos 7:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kò si rò li ọkàn wọn pe, emi ranti gbogbo ìwa-buburu wọn: nisisiyi iṣẹ ara wọn duro yi wọn ka; nwọn wà niwaju mi.

Hos 7

Hos 7:1-11