Hos 7:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kò si ti fi tọkàntọkàn ké pè mi, nigbati nwọn hu lori akete wọn: nwọn kó ara wọn jọ fun ọkà ati ọti-waini, nwọn si ṣọ̀tẹ si mi.

Hos 7

Hos 7:8-16