Hos 6:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni mo ṣe fi ãké ké wọn lati ọwọ awọn woli; mo ti fi ọ̀rọ ẹnu mi pa wọn: ki idajọ rẹ le ri bi imọlẹ ti o jade lọ.

Hos 6

Hos 6:2-8