Hos 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi o dàbi kiniun si Efraimu, ati bi ọmọ kiniun si ile Juda, emi, ani emi o fàya, emi o si lọ, emi o mu lọ, ẹnikẹni kì yio si gbà a silẹ.

Hos 5

Hos 5:6-15