Hos 13:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI Efraimu sọ̀rọ, ìwarìri ni; o gbe ara rẹ̀ ga ni Israeli; ṣugbọn nigbati o ṣẹ̀ ninu Baali, o kú.

Hos 13

Hos 13:1-6