Hos 11:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo kọ́ Efraimu pẹlu lati rìn, mo dì wọn mu li apa, ṣugbọn nwọn kò mọ̀ pe mo ti mu wọn lara dá.

Hos 11

Hos 11:2-10