Hos 10:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

A o si mu u lọ si Assiria pẹlu ẹbùn fun Jarebu ọba: Efraimu yio gbà itiju, oju yio si tì Israeli nitori igbìmọ rẹ̀.

Hos 10

Hos 10:4-15