Hos 10:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nisisiyi ni nwọn o wipe, Awa kò li ọba, nitoriti awa kò bẹ̀ru Oluwa; njẹ kili ọba o ṣe fun wa?

Hos 10

Hos 10:1-8