Hab 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe, wò o, emi gbe awọn ara Kaldea dide, orilẹ-ède ti o korò, ti o si yára, ti yio rìn ibú ilẹ na ja, lati ni ibùgbe wọnni, ti kì iṣe ti wọn.

Hab 1

Hab 1:1-11