Gẹn 9:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Ṣemu ati Jafeti mu gọgọwu, nwọn si fi le ejika awọn mejeji, nwọn si fi ẹhin rìn, nwọn si bò ìhoho baba wọn; oju wọn si wà lẹhin; nwọn kò si ri ìhoho baba wọn.

Gẹn 9

Gẹn 9:19-29