Gẹn 9:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si wi fun Noa pe, Eyiyi li àmi majẹmu na, ti mo ba ara mi ati ẹdá gbogbo ti o wà lori ilẹ dá.

Gẹn 9

Gẹn 9:9-19