Gẹn 8:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Noa si tẹ́ pẹpẹ fun OLUWA; o si mu ninu ẹranko mimọ́ gbogbo, ati ninu ẹiyẹ mimọ́ gbogbo, o si rú ẹbọ-ọrẹ sisun lori pẹpẹ na.

Gẹn 8

Gẹn 8:12-22