Gẹn 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ọdún kọkanlelẹgbẹta, li oṣù kini, li ọjọ́ kini oṣù na, on li omi gbẹ kuro lori ilẹ: Noa si ṣí ideri ọkọ̀, o si wò, si kiyesi i ori ilẹ gbẹ.

Gẹn 8

Gẹn 8:11-21