Gẹn 50:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu si goke lọ lati sin baba rẹ̀: ati gbogbo awọn iranṣẹ Farao, ati awọn àlagba ile rẹ̀, ati gbogbo awọn àlagba ilẹ Egipti si bá a goke lọ.

Gẹn 50

Gẹn 50:4-15