Gẹn 50:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi o ṣe ti nyin ni, ibi li ẹnyin rò si mi; ṣugbọn Ọlọrun mọ̀ ọ si rere, lati mu u ṣẹ, bi o ti ri loni lati gbà ọ̀pọlọpọ enia là.

Gẹn 50

Gẹn 50:18-26