Gẹn 5:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Gbogbo ọjọ́ Jaredi si jẹ ẹgbẹrun ọdún o dí mejidilogoji: o si kú.

21. Enoku si wà li ọgọta ọdún o lé marun, o si bí Metusela:

22. Enoku si ba Ọlọrun rìn li ọ̃dunrun ọdún lẹhin ti o bì Metusela, o si bí ọmọkunrin ati ọmọbinrin:

Gẹn 5