Gẹn 49:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ kiniun ni Judah; ọmọ mi, ni ibi-ọdẹ ni iwọ ti goke: o bẹ̀rẹ, o ba bi kiniun, ati bi ogbó kiniun; tani yio lé e dide?

Gẹn 49

Gẹn 49:1-11