Gẹn 49:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ifibú ni ibinu wọn, nitori ti o rorò; ati ikannu wọn, nitori ti o ní ìka: emi o pin wọn ni Jakobu, emi o si tú wọn ká ni Israeli.

Gẹn 49

Gẹn 49:5-11