Gẹn 49:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo wọnyi li awọn ẹ̀ya Israeli mejejila: eyi ni baba wọn si sọ fun wọn, o si sure fun wọn; olukuluku bi ibukún tirẹ̀, li o sure fun wọn.

Gẹn 49

Gẹn 49:27-33