Gẹn 48:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn ọmọ rẹ ti iwọ bí lẹhin wọn ni yio ṣe tirẹ, a o si ma pè wọn li orukọ awọn arakunrin wọn ni ilẹ iní wọn.

Gẹn 48

Gẹn 48:2-16