Gẹn 48:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sure fun wọn li ọjọ́ na pe, Iwọ ni Israeli o ma fi sure, wipe, Ki Ọlọrun ki o ṣe nyin bi Efraimu on Manasse: bẹ̃li o fi Efraimu ṣaju Manasse.

Gẹn 48

Gẹn 48:13-22