Gẹn 48:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sure fun Josefu, o si wipe, Ọlọrun, niwaju ẹniti Abrahamu ati Isaaki awọn baba mi rìn, Ọlọrun na ti o bọ́ mi lati ọjọ́ aiye mi titi di oni,

Gẹn 48

Gẹn 48:6-16