Gẹn 47:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kìki ilẹ awọn alufa ni kò rà; nitori ti awọn alufa ní ipín ti wọn lati ọwọ́ Farao wá, nwọn si njẹ ipín wọn ti Farao fi fun wọn; nitorina ni nwọn kò fi tà ilẹ wọn.

Gẹn 47

Gẹn 47:21-26