Gẹn 47:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati owo si tán ni ilẹ Egipti, ati ni ilẹ Kenaani, gbogbo awọn ara Egipti tọ̀ Josefu wá, nwọn si wipe, Fun wa li onjẹ: nitori kili awa o ṣe kú li oju rẹ? owo sa tán.

Gẹn 47

Gẹn 47:8-20