Gẹn 47:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Onjẹ kò si sí ni gbogbo ilẹ; nitori ti ìyan na mú gidigidi, tobẹ̃ ti ilẹ Egipti ati gbogbo ilẹ Kenaani gbẹ nitori ìyan na.

Gẹn 47

Gẹn 47:11-20