Gẹn 47:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu si fi baba rẹ̀ ati awọn arakunrin rẹ̀ joko, o si fun wọn ni iní ni ilẹ Egipti, ni ibi ãyo ilẹ, ni ilẹ Ramesesi, bi Farao ti pa li aṣẹ.

Gẹn 47

Gẹn 47:2-17