Gẹn 46:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluṣọ-agutan si li awọn ọkunrin na, ẹran sisìn ni iṣẹ wọn; nwọn si dà agbo-ẹran ati ọwọ́-ẹran wọn wá, ati ohun gbogbo ti nwọn ní.

Gẹn 46

Gẹn 46:28-34