Gẹn 46:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn ọmọ Josefu ti a bí fun u ni Egipti jẹ́ ọkàn meji; gbogbo ọkàn ile Jakobu, ti o wá si ilẹ Egipti jẹ́ ãdọrin ọkàn.

Gẹn 46

Gẹn 46:19-34