Gẹn 46:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn ọmọ Judah; Eri ati Onani, ati Ṣela, ati Peresi, ati Sera: ṣugbọn Eri on Onani ti kú ni ilẹ Kenaani. Ati awọn ọmọ Peresi ni Hesroni on Hamulu.

Gẹn 46

Gẹn 46:7-17