Gẹn 45:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, ẹ máṣe binujẹ, ki ẹ má si ṣe binu si ara nyin, ti ẹnyin tà mi si ihin: nitori pe, Ọlọrun li o rán mi siwaju nyin lati gbà ẹmi là.

Gẹn 45

Gẹn 45:3-11