Gẹn 45:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun u pe, Josefu mbẹ lãye sibẹ̀, on si ni bãlẹ gbogbo ilẹ Egipti. O si rẹ̀ Jakobu dé inu nitori ti kò gbà wọn gbọ́.

Gẹn 45

Gẹn 45:21-28