Gẹn 45:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o si ròhin gbogbo ogo mi ni Egipti fun baba mi, ati ti ohun gbogbo ti ẹnyin ri; ki ẹnyin ki o si yara, ki ẹ si mú baba mi sọkalẹ wá ihin.

Gẹn 45

Gẹn 45:8-23