Gẹn 45:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibẹ̀ li emi o si ma bọ́ ọ; nitori ọdún ìyan kù marun si i; ki iwọ, ati awọn ara ile rẹ, ati ohun gbogbo ti iwọ ní, ki o má ba ri ipọnju.

Gẹn 45

Gẹn 45:6-17