Gẹn 44:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun u pe, Ẽṣe ti oluwa mi fi sọ irú ọ̀rọ wọnyi? Ki a má ri pe awọn ọmọ-ọdọ rẹ ṣe bi irú nkan wọnyi.

Gẹn 44

Gẹn 44:4-16