Gẹn 44:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si nwá a kiri, o bẹ̀rẹ lati ẹgbọ́n wá, o si pin lọdọ abikẹhin: a si ri ago na ninu àpo Benjamini.

Gẹn 44

Gẹn 44:6-15