Gẹn 44:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Njẹ ki o si ri bẹ̃ gẹgẹ bi ọ̀rọ nyin: ẹniti a ba ri i li ọwọ́ rẹ̀ on ni yio di ẹrú mi, ẹnyin o si ṣe alailẹṣẹ.

Gẹn 44

Gẹn 44:3-20