Gẹn 43:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si joko niwaju rẹ̀, akọ́bi gẹgẹ bi ipò ibí rẹ̀, ati abikẹhin gẹgẹ bi ipò ewe rẹ̀: ẹnu si yà awọn ọkunrin na si ara wọn.

Gẹn 43

Gẹn 43:30-34