Gẹn 43:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu si yara; nitori ti inu yọ́ ọ si aburo rẹ̀: o wá ibi ti yio gbé sọkun; o si bọ́ si iyẹwu, o si sọkun nibẹ̀.

Gẹn 43

Gẹn 43:21-34