Gẹn 43:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati awa dé ile-èro, ti awa tú àpo wa, si kiyesi i, owo olukuluku wà li ẹnu àpo rẹ̀, owo wa ni pípe ṣánṣan: awa si tun mú u li ọwọ́ pada wá.

Gẹn 43

Gẹn 43:11-31