Gẹn 43:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin na si mú ọrẹ na, nwọn si mú iṣẹ́po owo meji li ọwọ́ wọn, ati Benjamini; nwọn si dide, nwọn si sọkalẹ lọ si Egipti, nwọn si duro niwaju Josefu.

Gẹn 43

Gẹn 43:12-18