Gẹn 42:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu li o si ṣe balẹ ilẹ na, on li o ntà fun gbogbo awọn enia ilẹ na; awọn arakunrin Josefu si wá, nwọn si tẹ̀ ori wọn ba fun u, nwọn dojubolẹ.

Gẹn 42

Gẹn 42:2-9