Gẹn 42:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Reubeni si da wọn li ohùn pe, Emi kò wi fun nyin pe, Ẹ máṣe ṣẹ̀ si ọmọde na; ẹ kò si fẹ̀ igbọ́? si wò o, nisisiyi, a mbère ẹ̀jẹ rẹ̀.

Gẹn 42

Gẹn 42:21-25