Gẹn 42:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Wò o, mo gbọ́ pe ọkà mbẹ ni Egipti: ẹ sọkalẹ lọ sibẹ̀, ki ẹ si rà fun wa lati ibẹ̀ wá; ki awa ki o le yè, ki a máṣe kú.

Gẹn 42

Gẹn 42:1-6