Gẹn 41:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li alá na ṣe dìlu ni meji fun Farao; nitoripe lati ọdọ Ọlọrun li a ti fi idi ọ̀ran na mulẹ, Ọlọrun yio si mú u ṣẹ kánkan.

Gẹn 41

Gẹn 41:24-37