Gẹn 41:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao sí wi fun Josefu pe, Emi lá alá, kò si si ẹnikan ti o le tumọ̀ rẹ̀: emi si gburó rẹ pe, bi iwọ ba gbọ́ alá, iwọ le tumọ̀ rẹ̀.

Gẹn 41

Gẹn 41:5-23