Gẹn 40:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ jíji li a jí mi tà lati ilẹ awọn Heberu wá: ati nihinyi pẹlu, emi kò ṣe nkan ti nwọn fi fi mi sinu ihò-túbu yi.

Gẹn 40

Gẹn 40:10-20