Gẹn 4:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Kaini pe, Nibo ni Abeli arakunrin rẹ wà? O si wipe, Emi kò mọ̀; emi iṣe olutọju arakunrin mi bi?

Gẹn 4

Gẹn 4:1-15