Gẹn 39:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi ohun gbogbo ti o ní si ọwọ́ Josefu; kò si mọ̀ ohun ti on ní bikoṣe onjẹ ti o njẹ. Josefu si ṣe ẹni daradara ati arẹwà enia.

Gẹn 39

Gẹn 39:2-8